Notice of rights and entitlements Yoruba (PACE Code C) (accessible version)
Updated 27 January 2020
Ranti aw畛n 畉t畛 r畉 ni igba ti o wa ni atim畛le
Aw畛n 畉t畛 ti a Pese fun 畛 ni yi a se onigb畛w畛 fun lab畉 ofin ni oril畉-ede England ati Wales ati pe a gba p畉lu j畛 lori 畉t畛 r畉 si iwifun ninu ilana iwadi ti iwa buburu.
Aw畛n 畉t畛 r畉 ni ile i畊a差 ag畛 畛l畛pa ni a k畛 si ibi
A si tun ni aw畛n alaye ni 畉kur畉r畉 ni ori 畉s畉 kinni (1) titidi ori 畉s畉 k畛kanla (11).
畉kur畉r畉 alaye wa ninu Iwe Ilana fin ti 畛l畛pa C.
-
S畛 fun 畛l畛pa ti o ba f畉 ki agb畉j畛ro kan o ran 畛 l畛w畛 ni igba ti o ba wa ni ag畛 畛l畛pa. Eyii j畉 畛f畉.
-
S畛 fun 畛l畛pa ti o ba ni 畉nik畉ni ti o f畉 s畛 ibi ti o wa f炭n. Eyii j畉 畛f畉.
-
S畛 fun 畛l畛pa ti o ba f畉 wo aw畛n ofin w畛n- eyi j畉 Ilana Ofin Ise w畛n.
-
S畛 fun 畛l畛pa ti o ba nilo it畛ju ara. S畛 fun 畛l畛pa ti ara r畉 ko ba ya tabi ti o ba fi ara s竪竪se. 畛f畉 ni ile iwosan.
-
Ti a ba bi o ni ibeere nipa aw畛n 畉s畉 kan ti a fura si, o ko nilo lati s畛 ohunkohun. 畉w畉, o le se akoba fun aroye r畉 ti o ko ba dahun si ibeere ohun kan eyiti o nilo toba ya ni ile 畉j畛. Ohun kohun ti o ba s畛 ni a o lo g畉g畉bi 畉ri fun 畛.
-
畛l畛pa ni lati se alaye fun 畛 lori 畉s畉 ti a ro pe o da ati idi ti a fi mu 畛 ti a si fi 畛 si inu atim畛le.
-
畛lo畛pa ni lati j畉 ki iw畛 tabi agb畉j畛ro r畉 ri aw畛n iwe ak畛sil畉 ati ipam畛 fun idi ti a fi mu 畛 ti o si wa ni t狸m畛 l辿 ti nipa asiko r畉 ni ag畛 畛l畛pa.
-
Ti o ba nilo atum畛 ede, 畛l畛pa naa gb畛d畛 pese 畛kan fun 畛. O le ni aw畛n iwe ti a tum畛 p畉lu. Eyii j畉 畛f畉.
-
S畛 fun 畛l畛pa ti o kii ba se 畛m畛 oril畉-ede Britain ti o si f畉 kan si aj畛 tabi a畊oju oril畉-ede r畉 abi o f畉 ki a s畛 fun w畛n pe o wa ninu atim畛le. Eyii j畉 畛f畉.
-
畛l畛pa ni lati s畛 iye igba ti o ma fi wa ninu atim畛le fun 畛.
-
Ti a ba fi 畉sun kan 畛 ti 畉j畛 r畉 si de ile 畉j畛, iw畛 tabi agb畉j畛ro r畉 ni 畉t畛 lati ri iwe ip畉j畛 ki igb畉j畛 to b畉r畉.
Ti awon 畉t畛 w畛nyi ko ba da 畛 loju, , s畛 fun 畛l畛pa alamojuto naa
Wo aw畛n oju-iwe akoj畛 naa fun aw畛n alaye ni 畉kunr畉r畉 nipa bi 畛l畛pa se y畉 ki o se abojuto ati it畛ju r畉.
畉ya Akiyesi aw畛n 畉t畛 ati Aj畉m畛nu ni ipa lati 21 August 2019 (ojo kanle logun, osu kejo odun 2019)
J畛w畛 fi iwifun yi pam畛 ki o si ka-a ni kiakia. Yo ran 畛 l畛w畛 lati se aw畛n ipinnu nigba ti o wa ni ag畛 畛l畛pa.
1. Gbigba agb畉j畛ro lati ran 畛 l畛w畛.
- Agb畉j畛ro le ran 畛 l畛w畛 o si le fun 畛 ni im畛ran nipa ofin.
- B鱈b竪竪r竪 lati s畛r畛 p畉lu agb畉j畛ro ko j畉ki o ri bii wipe o ti se ohun ki ko bojumu.
- Olopa Alatim畛le gb畛d畛 beere l畛w畛 r畉 bi o ba f畉 im畛ran agb畉j畛ro. Eyii j畉 畛f畉.
- Aw畛n 畛l畛pa gb畛d畛 j畉ki o ba agb畉j畛ro s畛r畛 ni igbakugba, 畛san tabi asaal畉, nigbati o bawa ni ag畛 畛l畛pa.
- Bi o ba beere fun im畛ran ofin, a ki nsaba gba ki aw畛n 畛l畛pa beere ibeere kankan l畛wo畛 r畉 titi ti o fi ni anfaani lati ba agb畉jo畛ro kan s畛r畛. Nigbati aw畛n 畛l畛pa ba beere aw畛n ibeere l畛w畛 r畉, o le beere fun agb畉j畛ro lati wa ninu yara p畉lu r畉.
- Bi o ba ti s畛fun aw畛n 畛l畛pa wipe o ko f畛 im畛ran ofin sugbon o wa yi 畛kan r畉 pada, s畛 fun 畛l畛pa alatim畛le ti yoo wa ran 畛 l畛w畛 lati kan si agb畉j畛ro kan.
- Bi agb畉j畛ro kan ko ba y畛ju tabi kan si 畛 ni ag畛 畛l畛pa, tabi o nilo lati ba agb畉j畛ro kan s畛r畛 l畉香差kansi, beere l畛w畛 aw畛n 畛l畛pa lati kan si w畛n l畉香差kansi.
Im畛ran ofin 畛f畉 nipa aw畛n ohun ti ko lewu pup畛:
- Ninu awon 畉j畛 k畛畛kan ti ko lewu pup畛, aw畛n ak畛畊a差m畛畊a差 oludam畛ran lati I畊a差 Aabo Arufin (CDS) taara nikan lo le gbani n im畛ran ofin 畛f畉 lori 畉r畛 ibara畉nis畛r畛 ayafi ti agb畉j畛ro ba wa lati ag畛 畛l畛pa, bii:
- Aw畛n 畛lo畛pa f畉 beere aw畛n ibeere nipa 畉s畉 kan tabi se eto idanimo eleri.
- o nilo iranl畛w畛 lati 畛d畛 agbalagba ti o y畉高. Wo Aw畛n eniyan ti o nilo iranl畛w畛.
- o kole soro lori 畉r畛 ibara畉nis畛r畛, tabi
- o fi 畉sun ihuwasi odi lile kan aw畛n 畛l畛pa.
Igbati igbani n im畛ran ofin 畛f畉 lori 畉r畛 ibara畉nis畛r畛 ki se fun I畊a差 Aabo Arufin (CDS) Taara nikan:
-
O le beere lati ba agb畉j畛ro kan ti o m畛 s畛r畛 o ko si nilo lati sanwo ti w畛n ba se ise iranw畛 agb畉j畛ro. Bi o ko ba m畛 agb畉j畛ro kankan tabi a ko le kan si agb畉j畛ro ti o m畛, o le ba agb畉j畛ro ti o wa l畉nu i畊a差 s畛r畛. Eyii j畉 畛f畉.
-
Agb畉j畛ro ti o wa l畉nu i畊a差 koni ohunkohun se p畉lu aw畛n 畛l畛pa.
Lati seto fun im畛ran ofin 畛f畉:
-
Aw畛n 畛l畛pa yo kan si Ibi Ipe Agb畉j畛ro Aabo (DSCC). DSCC naa yo seto fun lati gba imoran ofin, lati 畛d畛 CDS Taara, lati 畛d畛 agb畉j畛ro kan ti o ti beere fun tabi lati 畛d畛 Agb畉j畛ro ti o wa lenu i畊a差 naa.
-
DSCC ati CDS Taara naa j畉 aw畛n i畊a差 ara-畉ni to nseto imoran ofin 畛f畉 ti ko si ni ohunkohun se p畉lu aw畛n 畛l畛pa.
Bi o ba f畉 sanwo fun im畛ran ofin funra r畉:
- Ni gbogbo igba o le san owo fun im畛ran ofin ti o ba f畉 b畉.
- Nigbati igbani n im畛ran ofin 畛f畉 lori 畉r畛 ibara畉nis畛r畛 wa fun CDS Taara nikan o si tun le ba agb畉j畛ro ti o f畉 s畛r畛 lori 畉r畛 ibara畉nis畛r畛 bi o ba f畉 b畉, sugbon iranw畛 ofin ko ni sanwo fun w畛won si le ni ki o sanwo fun w畛n. DSCC naa yo ba 畛 kan si agbejoro r畉.
- O l畉t畛 lati ba agb畉j畛ro ti o yan s畛r畛 ni k畛k畛 lori 畉r畛 ibara畉nis畛r畛 tabi w畛n le pinnu lati wa ri 畛 ni ag畛 畛l畛pa.
- Bi agb畉j畛ro ti o f畉 ko ba see kan si, aw畛n 畛l畛pa si le pe DSCC naa lati seto im畛ran ofin 畛f畉 lati 畛d畛 Agb畉j畛ro ti o wa l畉nu i畊a差.
2. Sis畛 fun 畉nikan wipe o wa ni ag畛 畛l畛pa
- O le beere pe ki aw畛n 畛l畛pa ba 畛 kan si 畉nikan ti o y畉 lati m畛 pe o wa ni ag畛 畛l畛pa. Eyii j畉 畛f畉.
- W畛n yo ba 畛 kan si 畉nikan ni kiakia.
3. Wiwo aw畛n Ofin Ise
- Awon Ofin Ise j畉 aw畛n ofin ti yo s畛 ohun ti aw畛n 畛l畛pa lese ati ohun ti w畛n ko le se nigbati o ba wa ni ag畛 畛l畛pa.
- Aw畛n 畛l畛pa yo j畉ki o ka Awon Ofin Ise naa, sugbon o ko le seyi ti yo ba da aw畛n 畛l畛pa duro nipa wiwadi boya o ti rufin.
- Bi o ba fe ka Aw畛n Ofin Ise naa, so fun 畛l畛pa Alatim畛le naa
4. Gbigba iranw畛 iwosan ti ara r畉 ba ya tabi ti o ba sese
- S畛 fun aw畛n 畛l畛pa bi ara r畉 ko ba ya tabi nilo oogun tabi ti o ba sese. W畛n yo pe dokita tabi n畛畛si tabi ak畛畊a差m畛畊a差 iwosan miiran 畛fe畉 si ni.
- A le gba o laaye lati lo oogun tir畉, sugb畛n aw畛n 畛l畛pa yo k畛k畛 y畉wo naa. N畛畛si kan yo k畛k畛 ri 畛 na, sugb畛n aw畛n 畛l畛pa yo rans畉 pe dokita kan bi o ba nilo 畛kan. O le beere lati ri dokita miiran, sugb畛n o le ni lati sanwo fun eyi.
5. 畉t畛 lati wa ni idak畉
Ti a ba beere ibeere l畛w畛 r畉 nipa 畉s畉 ti a fura si, o ko nilo lati s畛 ohunkohun.
畉w畉, o le se akoba fun aroye r畉 ti o ko ba dahun si ibeere ohun kan eyiti o nilo toba ya ni ile 畉j畛.
Ohun kohun ti o ba s畛 ni a o lo g畉g畉bi 畉ri fun 畛.
6. Mim畛 nipa 畉s畉 ti a fura si pe o s畉 ati mim畛 idi ti a fii mu o ati ti 畛 m畛le
- 畛l畛pa gb畛d畛 s畛 nipa iru 畉s畉 ti w畛n ro pe o ti da.. Eyi p畉lu igba ati ibi ti w畛n ro pe o ti s畉.
- 畛l畛pa gb畛d畛 s畛 idi ti wo畛n fi ro pe o s畉 畉s畉 naa fun 畛 ati idi ti w畛n fi gbagb畛 pe o y畉 ki aw畛n mu 畛.
- Ni ag畛 畛l畛pa, 畛l畛pa naa gb畛d畛 s畛 idi ti w畛n fi gbagb畛 pe o y畉 fun atim畛se fun 畛.
- Ki a to bi 畛 ni ibeere kankan nipa 畉s畉 kankan, 畛l畛pa ni lati fun iw畛 ati agb畉j畛ro r畉 ni iwifun ti o to nipa ohun ti 畛l畛pa ro pe o se ki o le ba gba ara r畉 sil畉, sugb畛n kii se akoko ti yoo pa iwadi 畛l畛pa naa lara.
- Eyi wa fun aw畛n 畉s畉 miran ti aw畛n 畛l畛pa ro pe o se.
7. Wiwo aw畛n iwe ak畛sil畉 ati ipam畛 nipa m鱈m炭 ati itim畛le r畉.
- Ni igba ti o ba wa ni atim畛le ni ag畛 畛l畛pa, 畛l畛pa gb畛d畛:
- Ak畛sil畉 ninu iwe ipam畛 r畉, idi ti w畛n fi mu 畛 ati idi ti w畛n fi gbagb畛 pe o ye ki o wa ni atim畛le.
- Je ki iw畛 ati agb畉j畛ro r畉 wo iwe ak畛sil畉 r畉. 畛l畛pa aham畛 yoo seto eyi.
- Eyi wa fun aw畛n 畉s畉 miran ti olopa ro pe o s畉.
- 畛l畛pa gb畛d畛 gba ki iw畛 tabi agb畉j畛ro r畉 ni anfaani si aw畛n iwe ati ohun ti o y畉 lilo lati gbogun ti ofin ti o sokun fa mimu ati titi 畛 m畛le.
8. Gbigba atum畛 ede ati itum畛 aw畛n iwe k畛畛kan lati ran 畛 l畛w畛
- Ti o ko ba le s畛 tabi gb畛 ede G畉香差si, aw畛n 畛l畛pa yo seto fun enikan ti o ns畛 ede r畉 lati ran 畛 l畛w畛. Eyi j畉 畛f畉.
- Bi o ba j畉 odi tabi ni isoro lati s畛r畛, aw畛n 畛l畛pa yo seto fun Atum畛 Ede G畉香差si Ilu Britian lati ran 畛 l畛w畛. Eyi j畉 畛f畉.
- Ti o ko ba gb畛 tabi s畛 ede G畉香差si,, 畛l畛pa yo ba 畛 gba atum畛 ede lati s畛 idi ti o fi wa ni atim畛le. Eyi gb畛d畛 j畉 sise nigbogbo igba ti a ba se ipinnu lati fi 畛 si aham畛.
- L畉yin ipinnu k畛畛kan lati fi 畛 si aham畛 ati leyin ti fi 畉sun 畉s畉 kan 畛, 畛l畛pa gb畛d畛 fun 畛 ni iwe ak畛sil畉 idi atim畛le ati 畉sun 畉s畉 r畉 ni ede r畉, ayafi ti idi pataki lati ma se ba wa. Aw畛n ni:
- Ti o ba pinu pe o ko nilo ak畛sil畉 naa lati fi gba arar畉 sil畉 nitori pe o ni oye kikun nipa ohun ti o ns畉l畉 ati atunb畛tan aini iwe ak畛sil畉yi ti o si ti ni anfaani lati bi agb畉j畛ro fun iranl畛w畛 ati se ipinnu. O gb畛d畛 f畛w畛 si nipa iwe kik畛. -Toba j畉 nipa itum畛 ede 畛l畛r畛 tabi akoj畛 nipa atum畛 ede dipo kik畛 itum畛 ede ni yoo to fun 畛 lati gba ara r畉 sil畉 ti o si ni oye ohun to ns畉l畉. 畛l畛pa alaham畛 gb畛d畛 f畛w畛 si eyi.
- Nigbati aw畛n 畛l畛pa ba beere ibeere l畛w畛 r畉 ti w畛n ko si gba ohun sil畉, atum畛 ede naa yoo ka aw畛n ibeere ati idahun r畉 sil畉 ni ede tire. O ni anfaani lati y畉 eyi wo ki o to f畛w畛 sii g畉g畉bi ak畛sil畉 to y畉.
- Bi o ba f畉 s畛 gbolohun 畛r畛 kan fun aw畛n 畛l畛pa, atum畛 ede naa yoo se 畉da gbolohun naa ni ede tir畉 fun 畛 lati y畉香差wo ki o si f畛w畛 pe o t畛.
- O si tun l畉t畛 si itum畛 ede akiyesi yi. Ti ko ba si itum畛 ede lar畛w畛to, o nilo lati gba iwifun naa nipas畉 atum畛 ede kan ki o si fun 畛 ni itum畛 ede naa lai fi akoko sofo.
9. Kikan si aj畛 tabi a畊oju oril畉-ede r畉
Ti o kii ba se 畛m畛 oril畉-ede Britain, o le s畛 fun aw畛n 畛l畛pa wipe o f畉 kan si Aj畛 Agba, Aj畛 Asoju tabi Igbim畛 Asoju Oril畉-ede r畉 lati s畛 ibi ti o wa fun w畛n ati idi ti o fi wa ni ag畛 畛l畛pa. W畛n tun le b畉 o wo ni ik畛k畛 tabi seto fun agb畉j畛ro lati ri 畛.
10. Igba wo lole wa ni atim畛le da
- O le wa ni atim畛le fun wakati 24 lai gbe 畛 l畛 sile 畉j畛. Eyi le p畉ayafi ti adaj畛 tabi adaj畛 agba ni ile-畉j畛 giga ba da 畉j畛 naa ti 畛ga 畛l畛pa tabi ile-畉j畛 si gba laaye lati s畉l畉. L畉yin wakati 36, ile-畉j畛 nikan lole gba aw畛n 畛l畛pa laaye lati ti 畛 m畛le fun akoko die si lai pe 畛 l畉j畛.
- Lati igba de igba 畛ga 畛l畛pa kan gb畛do ma wo 畉j畛 r畉 lati ri daju pe a o da 畛 duro si ag畛 畛l畛pa. Eyi ni a npe ni atuny畉wo, 畛l畛pa naa si ni 畛l畛pa ay畉wo. Afi ti o ko ba si ni ipo ilera, o ni 畉t畛 lati le s畛r畛 si ipinnu yi nipa kik畛 iwe tabi sis畛 fun 畛l畛pa ay畉wo tabi lori ala amuhunmaworan kan. Agb畉j畛ro r畉 naa ni 畉t畛 si 畛r畛 sis畛 lori eyi, dipo r畉.
- Ti 畛l畛pa ay畉wo ko ba fi 畛 sil畉, a ni lati m畛 bose j畉 ati idi to wa lak畛sil畉 ninu ak畛sil畉 aham畛 r畉.
- Ti atim畛le r畉 ko ba nilo, a gb畛d畛 fi 畛 sil畉. Ti aw畛n 畛l畛pa ba s畛 fun 畛 pe aw畛n f畉 t畉siwaju lati se iwaadi 畉sun naa, a o fi 畛 sil畉 boya nipa gbigba beli tabi aigba beli. To ba j畉 beli, w畛n gb畛d畛 fun 畛 ni iwe afiyesi lati s畛 fun 畛 pe o gb畛d畛 pada si ag畛 畛l畛pa ati nipa ohunkohun to ba r畛 m畛 beli r畉.
- Ti aw畛n 畛l畛pa ba f畉 beere pe ki ile-畉j畛 fi kun akoko itim畛le r畉:
- O ni lati wa ni ile 畉j畛 fun ij畉j畛 ayafi ti eto ala amohunmaworan ba wa, ki o le ba ri ati gb畛 aw畛n eniyan ninu ile 畉j畛 aw畛n naa yoo si le ri ati gb畛 畛.
- A o le seto ala amohunmaworan ayafi ti 畛l畛pa alabojuto s畛 pe o bojumu, agb畉j畛ro kan ba ti gba 畛 nim畛ran nipa ilo r畉 ati ti iw畛 naa ba f畛w畛 si.
- O gb畛d畛 gba 畉da iwifun naa ti o s畛 fun ile-畉j畛 nipa 畉ri ati idi ti 畛l畛pa se f畉 ko wa ni aham畛.
- O ni 畉t畛 lati ni agb畉j畛ro kan p畉lu r畉 fun ij畉j畛 ni ile 畉j畛.
- A o gba 畛l畛pa laye lati fi 畛 si aham畛 ti ile 畉j畛 ba gbagb畛 pe o y畉 ati wipe ki aw畛n 畛l畛pa nse iwadi 畛r畛 daadaa lai fi akoko sofo.
- Ti aw畛n 畛l畛pa ba ni 畉ri to daju lati fi ran 畛 l畛 si ile 畉j畛, a le pe 畛 l畉j畛 ni ag畛 畛l畛pa tabi nipa ifirans畉, pe ki o fi oju ba ile 畉j畛 fun idaj畛.
11. Anfaani si 畉ri ti 畛r畛 r畉 ba l畛 si ile 畉j畛
Ti a ba fi 畉sun 畉s畉 kan kn 畛, iw畛 tabi agb畉j畛ro r畉 ni lati ri 畉ri ti a fi tako 畛 ati 畉ri ti o le ran 畛 l畛w畛 lati gba ara r畉 sil畉.. Eyi gb畛d畛 waye ki igb畉j畛 r畉 to b畉r畉. 畛l畛pa ati awon Ilana Ise Idajo gb畛d畛 seto eyi ki w畛n si pese anfaani si aw畛n iwe ti o y畉.
Aw畛n ohun miiran lati m畛 nipa wiwa ni Ag畛 畛l畛pa
Bi o se y畉 ki a t畛ju ati mojuto 畛
Aw畛n ak畛sil畉 yii s畛 fun 畛 nipa ohun ti o le reti nigbati a ba fi 畛 si ag畛 畛l畛pa. Lati wadi sii, beere alti ri Awon Ise Ofin. Eyi p畉lu akoj畛 ibi ti o ti le ri iwifun sii nipa 畛k畛畛kan nipa aw畛n ohun w畛nyi. Beere l畛w畛 畛l畛pa aham畛 bi o ba ni ibeere Kankan.
Aw畛n eniyan ti o nilo iranl畛w畛
- Bi o ko ba ti pe omo odun mejidilogun (18) tabi ti o ni ipalara, fun ap畉香差r畉 ti o ni isoro 畉k畛 tabi ailera 畛p畛l畛, o ni 畉t畛 si 畉nikan lati wa p畉lu r畉 nigbati aw畛n 畛l畛pa ba nse ohun kan. 畉ni yi ni agba to y畉高 w畛n yo si gba 畉da akiyesi yi.
- Agba r畉 kan yoo ran 畛 l畛w畛 lati m畛 ohun to ns畉l畉 yoo si ba 畛 samojuto aw畛n ipinnu r畉. O gb畛d畛 wa p畉lu r畉 nigbati aw畛n 畛l畛pa ba ns畛 fun 畛 nipa aw畛n 畉香 r畉 ati idi ti a fi wa ni ag畛 畛l畛pa. O tun gb畛d畛 wa p畉lu r畉 nigbati 畛l畛pa ba nka aw畛n ikil畛 畛l畛pa fun 畛.
- Agba r畉 to y畉 naa le beere agb畉j畛ro fun 畛.
- O le ba agb畉j畛ro r畉 s畛r畛 laisi agba r畉 to y畉 ninu yara naa bi o ba f畉.
- Aw畛n 畛l畛pa naa le nilo lati se ohun kan ninu aw畛n ohun akoj畛 to wa nisale yi nigbati o ba wa ni ag畛 ol畛pa. Ayafi ti aw畛n akanse idi ba wa, agba r畉 ti o y畉 gb畛d畛 wa p畉lu r畉 fun gbogbo akoko naa bi aw畛n 畛l畛pa ba se ohunkohun ninu aw畛n w畛nyi:
- Fi 畛r畛 wa 畛 l畉nu wo tabi beere pe ki f畛w畛 si iwe kik畛 tabi aw畛n ak畛sil畉 畛l畛pa.
- B畛 ju as畛 ita r畉 l畛 lati y畉 畛 wo.
- T畉ka, ya aworan tabi ay畉wo idanim畛 (DNA) tabi aw畛n ay畉wo miiran.
- Se ohunkohun ti o niise p畉lu eto ida 畉l畉ri m畛.
- A gb畛d畛 fun agba r畉 ni aaye lati wa lar畛w畛to r畉 tabi lori 畉r畛 ibata畉nis畛r畛 lati ran 畛 l畛w畛, nigbati aw畛n 畛l畛pa ba nse ay畉wo 畉sun r畉 lati rii boya o ma wa ni atim畛le sii.
- Ti agba r畉 ba ri aaye, w畛n gb畛do wa nib畉 nigbati 畛l畛pa naa ba nfi 畉sun kan 畛.
Gbigba alaye nipa akoko r畉 ni ag畛 畛l畛pa
-
Gbogbo ohun ti o ba s畉l畉 si 畛 nigbati o ba wa ni ag畛 畛l畛pa ni a ka sil畉 Eyi ni a npe ni Akasil畉 Aham畛.
-
Nigbati o ba kuro ni ag畛 畛l畛pa naa, iw畛, agb畉j畛ro r畉 tabi agba r畉 ti o y畉 le beere fun 畉da Akasil畉 Aham畛. Aw畛n 畛l畛pa ni lati fun 畛 ni 畉da Akasil畉 Aham畛 r畉 ni kop畉kop畉.
-
O le beere l畛w畛 aw畛n 畛l畛pa fun 畉da Akasil畉 Aham畛 r畉 titi di osu 12 l畉yin ti o ti kuro ni ag畛 畛l畛pa.
Biba aw畛n eniyan s畛r畛
- P畉lu biba agb畉j畛ro s畛r畛 ati sis畛 fun 畉nikan nipa atim畛le r畉 a o ma tun gba 畛 laaye lati se ipe kan.
- Beere l畛w畛 aw畛n 畛l畛pa bi o ba f畉 pe.
- O si tun le beere fun kalamu ati iwe pelebe.
- O le ni aw畛n alejo sugb畛n 畛l畛pa aham畛 le k畛 lati gba iy畉n.
Ile 畉w畛n r畉
- Bi o ba seese o y畉 ki o da wa ninu ile 畉w畛n.
- O y畉 ki o m畛, l畛w畛畛r畛 ati ni 嘆ye.
- As畛 it畉 r畉 gb畛d畛 m畛 ki o si wa ni titodaadaa.
- A gb畛d畛 gba 畛 laaye lati lo ile iyagb畉 ki o si w畉.
Awon ohun ohun elo ti ara ilera, imototo ati itoju
- Won ni lati beere lowo re ti o ba fe ba wa soro ni ibi koko pelu okan ninu awon osise abojuto nipa ohun to jomo eto ara ti o nii se pelu ilera, imototo ati ohun elo ti o nilo tabi ti o jo mo e nigba ti o ba wa ni atimole.
- Olopa yo se eto lati pese ohun ti a lero pe o nilo lati ba aini re pade. Ti o ba fe, eni ti o ba e soro le je eya abo tabi ako bi tire.
- Ti o ba je obirin ti o tii pe omo odun 18 (meji dilogun) tabi ti o ju bee lo, a ni lati beere lowo re ti o ba fe tabi ti o ba ma nilo awon ohun ti fi se nkan osu ni igba ti o ba wa ni atimole ati wi pe a ni lati so fun e pe:
- gbogbo ohun elo ni a o pese fun o ni ofe -awon ohun ipaaro wa; ati -gbogbo ohun elo yii ni awon ebi re tabi ore re le pese fun o ni apo ara won ti awon osise abojuto wa ba fara mo o.
- Ti o ba je obirin ti ko tii pe omo odun 18 (meji dilogun), osise abojuto maa seto wi pe eni ti o je obirin wa ni ago olopa lati toju re ati pe won yo beere ti o ba fe ohun elo ti ara ati ti nkan osu
Awon as畛
Bi a ba gba aw畛n as畛 r畉 kuro l畛w畛 r畉, aw畛n 畛l畛pa gb畛d畛 pese as畛 omiran fun 畛.
Ounj畉 ati ohun mimu
A gb畛d畛 fun 畛 ni ounj畉 畉m畉ta (3) lojum畛 p畉lu aw畛n ohun mimu. O si tun le mu aw畛n ohun mimu laarin ounje.
Er辿 Idaraya
Bi o ba seese o y畉 ki a gba 畛 laaye nita lojoojum畛 fun at畉gun.
Nigbati aw畛n o畛l畛pa ba beere ibeere l畛w畛 r畉
- Iyara naa ye ki o m畛 , l畛w畛畛r畛 ati ni 嘆ye.
- O ko nilo lati dide duro.
- O y畉 ki aw畛n 畛l畛pa naa le s畛 oruk畛 w畛n ati ipo w畛n fun 畛.
- O y畉 ki o ni isinmi ni aw畛n akoko ounj畉 ati isimi fun ohun mimu l畉yin wakati meji.
- O y畉 ki a gba o laaye fun o kere ju isinmi wakati 8 ninu wakati 24 ti o fi wa ni atim畛le.
Aw畛n ohun elo Igbagb畛
S畛 fun o畛l畛pa ti o ba nilo ohunkohun ti yoo ran 畛 l畛w畛 lati se 畉sin r畉 nigbati o ba wa ni ag畛 畛l畛pa. W畛n le pese iwe 畉sin ati awon nklan miiran , g畉g畉 bi o se f畉.
Aw畛n akoko ti aw畛n ofin deede nyat畛
Gbigba agb畉j畛ro lati ran 畛 l畛w畛
Aw畛n akanse akoko kan wa ti aw畛n 畛l畛pa nilo lati yara beere awon ibeere kan l畛w畛 r畉 ki o to le ba agb畉j畛ro kan s畛r畛.. Iwifun nipa aw畛n akanse akoko w畛nyi ni a fihan ninu Aw畛n Ise Ofin. Eyi ns畛 ohun ti aw畛n 畛lo畛pa lese tabi eyi ti w畛n kole se nigbati o ba wa ni ag畛 畛l畛pa. Bi o ba f畉 ye aw畛n alaye naa wo, w畛n wa ni ipin 畛r畛 6.6 ti Ofin C ti Awon Ise Ofin naa.
Akoko akanse kan wa ti aw畛n 畛l畛pa koni j畉ki o s畛r畛 p畉lu agb畉j畛ro ti o ti yan. Ti eyi ba s畉l畉 a gb畛d畛 gba 畛 laaye lati yan agb畉j畛ro miiran. Bi o ba f畉 wo aw畛n alaye naa, w畛n wa ni Afikun B ti Ofin C ti Awon Ise Ofin naa.
Sis畛 fun 畉nikan wipe o wa ni ag畛 畛l畛pa
Awon akanse akoko kan wa ti aw畛n 畛l畛pa koni gba ki o kan si 畉nik畉ni. Iwifun nipa aw畛n akanse akoko w畛nyi wa ninu Awon Ise Ofin naa.
Bi o bafe wo ekunrere alaye naa, w畛n wa ni Afikun B ti Ofin C ti Awon Ise Ofin naa.
Aw畛n 畉s畉 畛ti mimu ati ogun oloro mimu lakoko iwak畛
Bi o ba wa lag畛 畛l畛pa nitori aw畛n 畉s畉 畛ti mimu ati ogun oloro mimu lakoko iwak畛, o ni 畉t畛 lati ba agb畉j畛ro s畛r畛. 畉t畛 naa koni wipe o le k畛 lati fun aw畛n 畛l畛pa ni eemi r畉, 畉j畉 tabi it畛 koda ti o ko ba tii ba agb畉j畛ro naa s畛r畛.
Idani duro labe Ofin Ilera ti Iye 1983
Aw畛n 畛l畛pa naa tun le da 畛 duro ni ag畛 畛l畛pa fun ay畉wo lab畉 Ofin Ilera 畛p畛l畛 ti o ko bati pe 畛m畛 畛dun mejidinlogun tabi ju b畉 l畛 atipe nitori ewu pe ihuwasi r畉 o fa ijamba lile abi iku fun 畛 tabi fun 畉lomiran, o ko lero pe ki a da 畛 gunl畉 si ibo miran. Bi a bati da 畛 duro lab畉 Ofin Ilera 畛p畛l畛 eyi ko tum畛 si wipe a ti mu 畛 fun 畉s畉 kankan.
Eyi tum畛 si wipe aw畛n 畛l畛pa gb畛d畛 seto fun 畛 lati ri dokita ati Ak畛畊a差m畛畊a差 Ilera 畛p畛l畛 ti a fun las畉 lati se ay畉wo naa. A gb畛d畛 y畉 o wo laarin wakati 24 ti o de ag畛 畛l畛pa, tabi ti a ti da 畛 duro si ag畛 畛l畛pa, sugb畛n aw畛n 畛l畛pa y畛 gbiyanju lati seto yi ni kiakia. Ni ag畛 畛l畛pa, akoko idaduro oni wakati 24 fun ay畉wo le l畛gun fun wakati 12 si ti dokita ba ro pe o y畉 ti 畛ga 畛l畛pa naa si f畛w畛 si. Ni akoko yii, aw畛n 畛l畛pa le gbe 畛 lo si ibi ti o y畉 kan lati j畉 ki ay畉wo naa seese.
Nigbati o ba nduro fun ay畉wo, aw畛n 畛l畛pa le seto fun 畛 lati ri Onis畉 Ilera ti a fun ni as畉. W畛n kole se ay畉wo naa, sugb畛n w畛n yo ran 畛 l畛w畛 p畉lu aw畛n ailera miiran ti o le ni ati ran 畛 l畛w畛 lati salaye ohun ti idanwo naa tumo si.
Aw畛n Alejo Aham畛 Olominira
Aw畛n ara ilu kan wa ti a ngba laaye lati w畛le si ag畛 畛l畛pa lai s畛t畉l畉. A npe w畛n ni alejo aham畛 olominira ti w畛n si nsi畊a差 naa latinuwa lati ri pe a nt畛ju aw畛n ti tim畛le daadaa ati lati le ni 畉t畛 w畛n.
O ko ni 畉t畛 lati ri aw畛n alejo aham畛 olominira tabi beere pe ki w畛 o b畉 畛 wo sugb畛n alej畛 kan le beere lati ri 畛. Bi alejo aham畛 olominira ba wa ki 畛 nigbati o wa ni aham畛 w畛n yo ma sis畉 lominira ara w畛n lati ri pe aabo wa fun it畛ju ati 畉t畛 r畉.
畉w畉, o ko nilo lati ba w畛n s畛r畛 bi o ko ba f畉.
Bi o ti le se ifisun
Bi o ba f畉 se 畉sun nipa bi a se nt畛ju r畉, beere lati ba 畛l畛pa kan ti o j畉 oluy畉wo tabi 畛ga s畛r畛. L畉yin ti a ti fi 畛 sil畉, o tun le ifisun ni ag畛 畛l畛pa yoowu, si 畛fiisi Aj畛 fun Ihuwasi 畛l畛pa (IOPC) tabi nipas畉 agb畉j畛ro kan tabi MP to nduro fun 畛.